Thesaurus
Themen / Metalanguage
30 Wörter
- àfòmọ́ Anbringen
- àfòmọ́ àárín Infix
- àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ Präfix
- àkànlò-èdè Idiom
- àkọtọ́ Orthographie, Rechtschreibungssystem
- àmì ohùn ìsàlẹ̀ Tiefton-Markierung (ernster Akzent)
- àmì ohùn òkè Hochton-Markierung (Akuter Akzent)
- àpólà Satz (Grammatik)
- àrànmọ́ Assimilierung (von Geräuschen)
- ẹ̀ka-èdè Dialekt
- fáwẹ̀lì àárín Zentraler Vokal
- fáwẹ̀lì àìránmúpè Orale Vokale
- fáwẹ̀lì ẹ̀yìn Rückenvokal
- fáwẹ̀lì iwájú vorderer Vokal
- ìbáramu fáwẹ̀lì Vokalharmonie
- ìhun gbólóhùn Satzstruktur
- ìhun sílébù Silbenstruktur
- ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè Sprachwissenschaft
- ìró Sprachgeräusche
- ìró àránmúpè Nasengeräusch
- ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ Wortbildung
- ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ Bedeutung eines Wortes, Definition
- ìwé atúmọ̀-èdè Wörterbuch
- ìyálò ọ̀rọ̀ Anleihen (von Wörtern)
- ìyípadà ohùn Tonwechsel
- onímọ̀ ẹ̀dá-èdè Linguist
- ọ̀rọ̀ alákànpọ̀ zusammengesetztes Wort
- ọ̀rọ̀ àyálò Kredit-Wort
- ọ̀rọ̀ onísílébù kan einsilbiges Wort
- ọ̀rọ̀ onísílébù púpọ̀ Polysyllabisches Wort