Tesauro
Temas / Numbers
214 palabras
- ààbọ̀ mitad
- ààbọ̀ ọjọ́ medio día
- àádọ́rin setenta
- àádọ́rùn-ún noventa
- àádọ́ta cincuenta
- àdánù pérdida
- àfikún adición, suplemento
- agogo mẹ́ta ti lù Son las tres en punto
- agolo estaño, lata; medida de la taza
- àkáǹtì cuenta bancaria
- àkọ́kọ́ primero
- àkọsílẹ̀ owó registro financiero, libro mayor
- àǹkà contar, número
- apá kan una parte, un lado
- àrún Cinco (5)
- àwọn kan algunos (personas)
- àwọn méjèèjì los dos de ellos
- díẹ̀ nínú algunos de
- díẹ̀ sí i un poco más
- dín kù disminuir, reducir
- díwọ̀n a medida
- dọ́gba sí igualar (en matemáticas)
- èje Siete (7)
- èjì Dos (2)
- èjìlá Doce (12)
- èkejì El otro, el segundo
- èlé intereses (sobre el dinero)
- èló cuanto
- èló lẹ ń tà á ¿Por cuánto lo vendes?
- èló ni gbogbo rẹ̀ ¿Cuánto por todo?
- èmi ni ìkẹyìn Soy el último
- ènìyàn bí ọgọ́rùn-ún Alrededor de un centenar de personas
- ènìyàn mélòó ló wà níbẹ̀ ¿Cuántas personas había?
- èrè àpapọ̀ beneficio bruto
- ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta quinientos
- ẹ̀ẹ́dógún Quince (15)
- ẹ̀ẹ̀kan una vez
- ẹ̀ẹ̀mejì dos veces
- ẹ̀ẹ̀mẹta tres veces
- ẹ̀fà Seis (6)
- ẹgbàá dos mil
- ẹgbẹ̀rin ochocientos
- ẹgbẹ̀rún mil
- ẹgbẹ̀rún márùn-ún ọ̀rọ̀ Cinco mil palabras
- ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá diez mil
- ẹgbẹ̀ta seiscientos
- ẹ ka á fún mi Contarlo por mí
- ẹ̀kan nínú mẹ́ta Uno de cada tres; un tercio
- ẹ̀kọ́ ìṣirò matemáticas (tema)
- ẹ lo òògùn yìí lẹ́ẹ̀mẹta lójúmọ́ Tome este medicamento tres veces al día
- ẹ mú ṣẹ́ńjì yín Aquí está tu cambio
- ẹni kìíní ló borí La primera persona ganó
- ẹnìkọ̀ọ̀kan cada persona
- ẹni ọdún envejecido (... años)
- ẹ̀rí ìsanwó recibo
- ẹ̀rin Cuatro (4)
- ẹ̀sán Nueve (9)
- ẹ̀ta Tres (3)
- ẹ tà á fún mi ní… Venderlo a mí por...
- ẹ̀wá Diez (10)