Tesauro
Temas / Numbers
214 palavras
- ààbọ̀ metade
- ààbọ̀ ọjọ́ meio dia
- àádọ́rin setenta
- àádọ́rùn-ún noventa
- àádọ́ta 50
- àdánù perda
- àfikún além disso, suplemento
- agogo mẹ́ta ti lù São três horas
- agolo lata, lata; copo de medida
- àkáǹtì conta bancária
- àkọ́kọ́ primeiro
- àkọsílẹ̀ owó registro financeiro, livro-razão
- àǹkà contagem, número
- apá kan uma parte, um lado
- àrún Cinco (5)
- àwọn kan alguns (Pessoas.)
- àwọn méjèèjì os dois
- díẹ̀ nínú alguns...
- díẹ̀ sí i um pouco mais
- dín kù diminuir, reduzir
- díwọ̀n medir
- dọ́gba sí igualar (em matemática)
- èje Sete (7)
- èjì Dois (2)
- èjìlá Doze (12)
- èkejì O outro, o segundo
- èlé interesse (em dinheiro.)
- èló quanto?
- èló lẹ ń tà á Por quanto você está vendendo?
- èló ni gbogbo rẹ̀ Quanto por tudo isso?
- èmi ni ìkẹyìn Eu sou o último
- ènìyàn bí ọgọ́rùn-ún Cerca de cem pessoas
- ènìyàn mélòó ló wà níbẹ̀ Quantas pessoas estavam lá?
- èrè àpapọ̀ lucro bruto
- ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta quinhentos
- ẹ̀ẹ́dógún Quinze (15)
- ẹ̀ẹ̀kan uma vez
- ẹ̀ẹ̀mejì duas vezes
- ẹ̀ẹ̀mẹta três vezes
- ẹ̀fà Seis (6)
- ẹgbàá dois mil
- ẹgbẹ̀rin oitocentos
- ẹgbẹ̀rún mil
- ẹgbẹ̀rún márùn-ún ọ̀rọ̀ Cinco mil palavras
- ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá dez mil
- ẹgbẹ̀ta seiscentos
- ẹ ka á fún mi Conte para mim
- ẹ̀kan nínú mẹ́ta Um em cada três, um terceiro
- ẹ̀kọ́ ìṣirò matemática (assunto)
- ẹ lo òògùn yìí lẹ́ẹ̀mẹta lójúmọ́ Tome este medicamento três vezes por dia
- ẹ mú ṣẹ́ńjì yín Aqui está o seu troco
- ẹni kìíní ló borí A primeira pessoa ganhou
- ẹnìkọ̀ọ̀kan cada pessoa
- ẹni ọdún envelhecido (... anos)
- ẹ̀rí ìsanwó recibo
- ẹ̀rin Quatro (4)
- ẹ̀sán Nove (9)
- ẹ̀ta Três (3)
- ẹ tà á fún mi ní… Vender para mim por...
- ẹ̀wá Dez (10)