Thésaurus
Thèmes / Numbers
214 mots
- ààbọ̀ moitié
- ààbọ̀ ọjọ́ une demi-journée
- àádọ́rin Soixante-dix
- àádọ́rùn-ún Quatre-vingt-dix
- àádọ́ta 50 ans
- àdánù perte
- àfikún addition, supplément
- agogo mẹ́ta ti lù Il est trois heures.
- agolo étain, boîte; mesure de la tasse
- àkáǹtì compte bancaire
- àkọ́kọ́ première
- àkọsílẹ̀ owó bilan financier, registre
- àǹkà nombre, numéro
- apá kan une partie, un côté
- àrún Cinq (5)
- àwọn kan quelques-uns (et de la population)
- àwọn méjèèjì Tous les deux.
- díẹ̀ nínú une partie de
- díẹ̀ sí i un peu plus
- dín kù pour diminuer, réduire
- díwọ̀n Mesurer
- dọ́gba sí à égal (en mathématiques)
- èje Sept (7)
- èjì Deux (2)
- èjìlá Douze (12)
- èkejì l'autre, le second
- èlé Intérêts (sur l'argent)
- èló combien
- èló lẹ ń tà á Combien vendez-vous ?
- èló ni gbogbo rẹ̀ Combien pour tout ça ?
- èmi ni ìkẹyìn Je suis le dernier.
- ènìyàn bí ọgọ́rùn-ún Une centaine de personnes
- ènìyàn mélòó ló wà níbẹ̀ Combien de personnes y avait-il ?
- èrè àpapọ̀ Bénéfice brut
- ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta cinq cents
- ẹ̀ẹ́dógún Quinze (15)
- ẹ̀ẹ̀kan une fois
- ẹ̀ẹ̀mejì deux fois
- ẹ̀ẹ̀mẹta trois fois
- ẹ̀fà Six (6)
- ẹgbàá deux mille
- ẹgbẹ̀rin huit cents
- ẹgbẹ̀rún mille
- ẹgbẹ̀rún márùn-ún ọ̀rọ̀ Cinq mille mots
- ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá dix mille
- ẹgbẹ̀ta six cents
- ẹ ka á fún mi Comptez-le pour moi.
- ẹ̀kan nínú mẹ́ta Un sur trois; un troisième
- ẹ̀kọ́ ìṣirò mathématiques (Sujet)
- ẹ lo òògùn yìí lẹ́ẹ̀mẹta lójúmọ́ Prenez ce médicament trois fois par jour
- ẹ mú ṣẹ́ńjì yín Voilà ta monnaie.
- ẹni kìíní ló borí La première personne a gagné
- ẹnìkọ̀ọ̀kan chaque personne
- ẹni ọdún âgés (... ans)
- ẹ̀rí ìsanwó reçu
- ẹ̀rin Quatre (4)
- ẹ̀sán Neuf (9)
- ẹ̀ta Trois (3)
- ẹ tà á fún mi ní… Vends-le-moi pour...
- ẹ̀wá Dix (10)